Nitori ọrẹkunrin ẹ to nilo owo, Ṣeun sa lọ nile l’Abẹokuta, lo ba ni wọn ji oun gbe ni

Spread the love

Nitori ọrẹkunrin ẹ to nilo owo, Ṣeun sa lọ nile l’Abẹokuta, lo ba ni wọn ji oun gbe ni

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta
Ṣeun Adekunle lorukọ ọmọbinrin ti ẹ n wo yii, ọmọ ọdun mẹtadinlogun(17) ni. Ọrẹkunrin ẹ ti wọn n pe ni Basit Ọlasunkanmi, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn ni wọn jọ duro pẹlu ṣẹkẹṣẹkẹ lọwọ yii, awọn mejeeji nii wọn ṣeto bi Ṣeun ṣe kuro nile, ti wọn wa n beere ẹgbẹrun lọna ẹẹdẹgbẹta Naira (500,000) lọwọ iya ọmọ naa ki wọn too le yọnda rẹ.
Alukoro ọlọpaa nipinlẹ yii, DSP Abimbọla Oyeyẹmi, ṣalaye pe iwadii awọn fi han pe Basit ti Ṣeun n fẹ yii lo fi ero ijinigbe naa si ọmọ yii lọkan. Alapata ẹran ni Basit gẹgẹ bo ṣe wi, oun lo nilo owo kan to si tori ẹ ba ọmọbinrin naa sọrọ pe ko sa kuro nile waa ba oun, ko si fi eyi to ku silẹ foun.

RELATED:  Qdot’s Producer, Antras Defrauds Artiste, Kelson With Zlatan’s Name
RELATED:  The original Otunba Lamba has arrived (Check out this Funny Video by Mr Benson)

Recommended Songs For You

RELATED:  Checkout photos of new speaker, Femi Gbajabiamila at Office
About Akingbade Mathew 3799 Articles
A certified Public relations practitioner, trained Journalist/Broadcaster, a Tv personality, A&R ,PR/Media consultant, Social Media Addict, it’s sure safe to say he is 100/% media and Entertainment. Also prolific Writer, Music/Entertainment expert with an Experience of over half a decade, and this has no doubt describe his persona in totality. He is referred by many as the skillful one with that million dollar idea or concept as well as marketing and selling it to the world. Email [email protected] call/whatsapp +2348167999058

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*